Easter Bonus: Onisegun nla wa nihin Jesu abanidaro (Yoruba Hymn)

Download Yoruba Hymn, Onisegun nla wa nihin Jesu abanidaro Mp3


Remember this powerful soul lifting Yoruba Hymn Onisegun nla wa nihin Jesu abanidaro? This song is one of the most popular and to be sincere my favorite of them all.

You can download Onisegun nla wa nihin
Jesu abanidaro below! Don’t forget to sing along using the hymn lyrics! Remain Bless as you worship!

Enjoy Below!

DOWNLOAD

(Yoruba Hymn) ONISEGUN NLA WA NIHIN

Onisegun nla wa nihin
Jesu abanidaro
Oro Re mu ni l’ara da
Agbo ohu ti JesuChorus
Iro didun lorin Seraf
Oruko didun n’nu enia
Orin t’o dun julo ni
Jesu, Jesu, JesuA fi gbogb’ ese re ji o
A gbo ohun ti Jesu
Rin lo s’orun l’alafia
Si ba Jesu de ade

Gbogb’ ogo fun Krist’ t’o jinde
Mo gbagbo nisisiyi
Mo f’oruko Olugbala
Mo fe oruko Jesu

Oruko Re l’eru mi lo
Ko si oruko miran
B’ okan mi ti nfe lati gbo
Oruko Re ‘yebiye

Arakunrin e ba mi yin
A yin oruko Jesu
Arabirin, gb’ohun s’oke
A yin oruko Jesu

Omode at’agbalagba
T’o fe oruko Jesu
Le gba ‘pe ‘fe nisisiyi
Lati sise fun Jesu

Dont Forget to Share this post..Thanks!

About the author

Oyegoke Samuel

I'm a Minister @RCCG, A Gospel/Tech Blogger | IT Support Engineer & Front End Website Designer

Leave a Comment